Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin

Fánrán yìí se àfihàn ipa tí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ irúgbìn ẹ̀gẹ́ (pákí) àti ànọ̀mọ́-aládídùn (kúkúndùkú) ńkó láti ri wípé èrè tó wà ní ìdíi òwò títa irúgbìn fún àwọn èso wọ̀nyí ní orílẹ̀ èdè Tànsáníà gbóòrò si. Fánrán yìí tún tan ìmọ́lẹ̀ sí àgbékalẹ̀ àti àwọn ìlànà àá tẹ̀lé tí ẹgbẹ́ yìí ń se àmúlò láti ri wípé...

Descripción completa

Detalles Bibliográficos
Autor principal: International Institute of Tropical Agriculture
Formato: Video
Lenguaje:suajili
Publicado: International Institute of Tropical Agriculture 2025
Acceso en línea:https://hdl.handle.net/10568/178263
_version_ 1855522777704955904
author International Institute of Tropical Agriculture
author_browse International Institute of Tropical Agriculture
author_facet International Institute of Tropical Agriculture
author_sort International Institute of Tropical Agriculture
collection Repository of Agricultural Research Outputs (CGSpace)
description Fánrán yìí se àfihàn ipa tí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ irúgbìn ẹ̀gẹ́ (pákí) àti ànọ̀mọ́-aládídùn (kúkúndùkú) ńkó láti ri wípé èrè tó wà ní ìdíi òwò títa irúgbìn fún àwọn èso wọ̀nyí ní orílẹ̀ èdè Tànsáníà gbóòrò si. Fánrán yìí tún tan ìmọ́lẹ̀ sí àgbékalẹ̀ àti àwọn ìlànà àá tẹ̀lé tí ẹgbẹ́ yìí ń se àmúlò láti ri wípé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ń rí ànfààní tó pèye, l’ọ́nà tí yíò mú ìlọsíwájú bá ìpèsè àti kátàkárà irúgbìn wònyí. Ọ̀kan pàtàkì nínú ìdí tí a fi gbé fánrán yìí kalẹ̀ ni láti se àfihàn fún àwọn àgbẹ̀ oní irúgbìn láti ibòmíràn, irúu àwọn ànfàní tó rò mó jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn. Nítorí náà, fánrán yìí se àfihàn bí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn yìí se ń fa ìtẹ̀síwájú, gbígbòòrò, àti ìsọdọ̀tun fún àwọn èso tí a ma ń gbìn láti ara gbòngbò, èso, igi, tàbí ẹ̀ka wọn.
format Video
id CGSpace178263
institution CGIAR Consortium
language Swahili
publishDate 2025
publishDateRange 2025
publishDateSort 2025
publisher International Institute of Tropical Agriculture
publisherStr International Institute of Tropical Agriculture
record_format dspace
spelling CGSpace1782632025-11-26T14:11:52Z Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin International Institute of Tropical Agriculture Fánrán yìí se àfihàn ipa tí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ irúgbìn ẹ̀gẹ́ (pákí) àti ànọ̀mọ́-aládídùn (kúkúndùkú) ńkó láti ri wípé èrè tó wà ní ìdíi òwò títa irúgbìn fún àwọn èso wọ̀nyí ní orílẹ̀ èdè Tànsáníà gbóòrò si. Fánrán yìí tún tan ìmọ́lẹ̀ sí àgbékalẹ̀ àti àwọn ìlànà àá tẹ̀lé tí ẹgbẹ́ yìí ń se àmúlò láti ri wípé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ń rí ànfààní tó pèye, l’ọ́nà tí yíò mú ìlọsíwájú bá ìpèsè àti kátàkárà irúgbìn wònyí. Ọ̀kan pàtàkì nínú ìdí tí a fi gbé fánrán yìí kalẹ̀ ni láti se àfihàn fún àwọn àgbẹ̀ oní irúgbìn láti ibòmíràn, irúu àwọn ànfàní tó rò mó jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn. Nítorí náà, fánrán yìí se àfihàn bí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn yìí se ń fa ìtẹ̀síwájú, gbígbòòrò, àti ìsọdọ̀tun fún àwọn èso tí a ma ń gbìn láti ara gbòngbò, èso, igi, tàbí ẹ̀ka wọn. 2025-11-07 2025-11-26T14:11:51Z 2025-11-26T14:11:51Z Video https://hdl.handle.net/10568/178263 sw Open Access International Institute of Tropical Agriculture International Institute of Tropical Agriculture. (2025). Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin. Ibadan, Nigeria: IITA
spellingShingle International Institute of Tropical Agriculture
Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title_full Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title_fullStr Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title_full_unstemmed Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title_short Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin
title_sort ije ki ere wa lori koro ogbin
url https://hdl.handle.net/10568/178263
work_keys_str_mv AT internationalinstituteoftropicalagriculture ijekierewalorikoroogbin