Ije Ki ere wa lori Koro Ogbin

Fánrán yìí se àfihàn ipa tí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ irúgbìn ẹ̀gẹ́ (pákí) àti ànọ̀mọ́-aládídùn (kúkúndùkú) ńkó láti ri wípé èrè tó wà ní ìdíi òwò títa irúgbìn fún àwọn èso wọ̀nyí ní orílẹ̀ èdè Tànsáníà gbóòrò si. Fánrán yìí tún tan ìmọ́lẹ̀ sí àgbékalẹ̀ àti àwọn ìlànà àá tẹ̀lé tí ẹgbẹ́ yìí ń se àmúlò láti ri wípé...

Descripción completa

Detalles Bibliográficos
Autor principal: International Institute of Tropical Agriculture
Formato: Video
Lenguaje:suajili
Publicado: International Institute of Tropical Agriculture 2025
Acceso en línea:https://hdl.handle.net/10568/178263
Descripción
Sumario:Fánrán yìí se àfihàn ipa tí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ irúgbìn ẹ̀gẹ́ (pákí) àti ànọ̀mọ́-aládídùn (kúkúndùkú) ńkó láti ri wípé èrè tó wà ní ìdíi òwò títa irúgbìn fún àwọn èso wọ̀nyí ní orílẹ̀ èdè Tànsáníà gbóòrò si. Fánrán yìí tún tan ìmọ́lẹ̀ sí àgbékalẹ̀ àti àwọn ìlànà àá tẹ̀lé tí ẹgbẹ́ yìí ń se àmúlò láti ri wípé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ń rí ànfààní tó pèye, l’ọ́nà tí yíò mú ìlọsíwájú bá ìpèsè àti kátàkárà irúgbìn wònyí. Ọ̀kan pàtàkì nínú ìdí tí a fi gbé fánrán yìí kalẹ̀ ni láti se àfihàn fún àwọn àgbẹ̀ oní irúgbìn láti ibòmíràn, irúu àwọn ànfàní tó rò mó jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn. Nítorí náà, fánrán yìí se àfihàn bí ẹgbẹ́ àgbẹ̀ oní irúgbìn yìí se ń fa ìtẹ̀síwájú, gbígbòòrò, àti ìsọdọ̀tun fún àwọn èso tí a ma ń gbìn láti ara gbòngbò, èso, igi, tàbí ẹ̀ka wọn.